Adaora Ukoh jẹ́ òṣèrébìnrin ilẹ̀ Nàìjíríà tó ti ṣàfihàn nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ fíìmù àgbéléwò bí i Thy Kingdom Come, Black Bra àti Lekki Wives. Òun ni olóòtú Divas Dynasty àti alábòójútó Adaora couture fún àwọn obìnrin tó tóbi gan-an.[1][2] Ó sọ̀rọ̀ lásìkò ìgbé àwọn Chibok girls.[3][4]

Adaora Ukoh
Ọjọ́ìbí27 Oṣù Kẹrin 1976 (1976-04-27) (ọmọ ọdún 48)
Anambra, Nigeria
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity of Lagos
Iṣẹ́Actress
Ìgbà iṣẹ́1995–present
Olólùfẹ́Basil Eriofolor
Àwọn ọmọ1

Ìgbésí ayé rẹ̀

àtúnṣe

Wọ́n bí Ada ní 27 April, ọdún 1976 ní Ipinle Anambra.[5][6] Ilé-ìwé St. John college ló lọ, ó sì kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìmọ̀ òfin ni University of Lagos.

Ó wọ ilé-iṣẹ́ fíìmù ṣị́ṣe nígbà tó wà ní ọmọdún mọ́kàndínlógún, ní ọdún 1995, tó kópa nínú fíìmù Deadly Affair. Lẹ́yìn náà ni ó kópa nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ fíìmù. Nínú fíìmù Lekki wives, ó kópa gẹ́gẹ́ bí i Miranda.[7] Àwọn ojúṣe rẹ̀ ò fi bẹ́ẹ̀ pọ̀nítorí ìwọ̀n àti bí ó ṣe tóbi tó, àmọ́ èrò rẹ̀ ni pé ẹ̀bùn ni ìrísí àti ìwọ̀n rẹ̀.[8][9][10] Adaora ní láti gẹ irun gorímápá nínú fíìmù Thy Kingdom Come, níbi tó ti ṣe bí opó.[11]

Ayé rẹ̀

àtúnṣe

Òṣèrébìnrin náà ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú Basil Eriofolor, wọ́n sì bí ọmọkùnrin kan.[12]

Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀

àtúnṣe

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "DIVAS DYNASTY HOSTED BY BIG BOLD AND BEAUTIFUL ACTRESS(ADAORA UKOH) DEBUTS ON AIR". Nigerian Voice. Retrieved 6 August 2022. 
  2. ". Adaora Ukoh Abumere Biography | Profile | Fabwoman". FabWoman | News, Style, Living Content For The Nigerian Woman (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 29 April 2019. Retrieved 6 August 2022. 
  3. BellaNaija.com (6 May 2014). "#BringBackOurGirls – Adaora Ukoh & Keira Hewatch Let their Shirts Do the Talking". www.bellanaija.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 6 August 2022. 
  4. "Adaora Ukoh & Keira Hewatch Let their Shirts Speak #BringBackOurGirls". T. S. B. News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 6 May 2014. Retrieved 6 August 2022. 
  5. Tayo, Ayomide O. (27 April 2015). "Lolo, Adaora Ukoh, Lisa Omorodion a year older today". Pulse Nigeria. Retrieved 6 August 2022. 
  6. izuzu, chibumga (27 April 2016). "7 things you should know about "Lekki Wives" actress". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 6 August 2022. 
  7. Nwogu, Precious 'Mamazeus' (12 July 2022). "A 'Lekki Wives' sequel is officially in the works!". Pulse Nigeria. Retrieved 6 August 2022. 
  8. nigeriafilms.com (30 November 2009). "'I want people to see me and get turned on.'----Adaora Ukoh". Modern Ghana (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 6 August 2022. 
  9. Staff, Daily Post (13 November 2011). "Adaorah Ukoh talks about discrimination against plus size people". Daily Post Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 6 August 2022. 
  10. demola (26 April 2020). "The secret of my success as a plus size actress – Adaora Ukoh -". The NEWS (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 6 August 2022. 
  11. "Actresses who dare to go bald in Movies". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 9 February 2013. Retrieved 6 August 2022. 
  12. Rapheal (13 April 2019). "My 20 hours experience in labour room –Adaora Ukoh". The Sun Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 6 August 2022. 
  13. "Lekki wives: The dust in the diamond". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 7 August 2013. Retrieved 6 August 2022. 
  14. izuzu, chibumga (27 October 2016). "20 years ago, Nollywood released the classic "Karishika"". Pulse Nigeria. Retrieved 6 August 2022.