Adebayo Adedeji
Adebayo Adedeji (1930-2018) ni a bini óṣu December ni Ijẹbu Ode jẹ economist ati akademi ọmọ órilẹ èdè nigeria. Arakunrin naa jẹ Comissioner ti federal órilẹ ede naigiria lori Economic development ati restruction lati ọdun 1971 dè 1975[1].
Adebayo Adedeji | |
---|---|
Professor Adedeji in 1986 | |
Ọjọ́ìbí | 21 December 1930 Ijebu-Ode, Nigeria |
Aláìsí | 25 April 2018 Lagos, Nigeria | (ọmọ ọdún 87)
Iṣẹ́ |
|
Igbèsi Ayè Arakunrin naa
àtúnṣeArakunrin naa gba óyè professor nigba ti ópè ọmọ ọdun mẹrin din logoji. Ni óṣu june, ọdun 1975 ni ayan Adebayo adedeji gẹgẹbi Executive secretary ti united nations economic commission fun ilẹ afirica to si wa ni ipó naa titi óṣu july ọdun 1991. Adedeji kọ plan ti action ti ilu èkó ti ọdun ọdun 1980 ti UN ati OAU si tẹwọgba. Nigba ti arakunrin naa pada si ilẹ naigiria ni ó da Africa center fun development ati strategic studies silẹ (ACDESS)[2].
Ni óṣu December, ọ̀dun 2010 nigba ti arakunrin naa pè ọmọ ọdun ọgọrin lẹyin to fẹyinti ni ó ló iyóku ninu igbesi ayè rè ni ilu rè Ijẹbu-Ode ni ipinlẹ ogun.
Adedeji ku ni irọlẹ óṣu April ni ọdun 2018 ni ilù èkó lẹyin to ṣè aisan ọlọjọ pipẹ. UNECA ṣè iranti ólógbe naa lati fi dalọla ni óṣu july ọdun 2018[3][4].
Ami Ẹyẹ ati Idanilọla
àtúnṣeAdebayo gba idanilọla ti national ti commander ti federal republic[5].
Itọkasi
àtúnṣe- ↑ https://www.premiumtimesng.com/news/more-news/266357-adebayo-adedeji-former-uneca-chief-dies-at-87.html
- ↑ https://www.uneca.org/ess/mr-adebayo-adedeji
- ↑ https://www.vanguardngr.com/2018/07/the-adebayo-adedeji-example-by-reuben-abati/amp/
- ↑ https://independent.ng/breaking-former-un-chief-adebayo-adedeji-dies-at-87/
- ↑ https://www.sunnewsonline.com/adebayo-adedeji-1930-2018/