Adebayo Babatunde Mohammed (ọjọ́-ìbí; ọjọ́ kẹta oṣù kìíní ọdún 1959) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà ati ọmọ ile ìgbìmò asofin kẹjọ ti o nsójú àgbègbè Ipaye/Malete/Oloru ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin Ìpínlẹ̀ Kwara . [1]