Adebayo Gbadebo

Adébáyọ̀ Gbádébọ̀ tí abí ní Ọgbọ̀njọ́ oṣù Karùn-ún, Ọdún 1974.(30 May 1974) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ẹlẹ́sẹ̀ àti ọ̀jan lára àwọn akọ́ni mọ̀ọ́gbá ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. [1]

Adebayo Gbadebo
Personal information
OrúkọAdébáyọ̀ Gbádébọ̀
Ọjọ́ ìbí30 Oṣù Kàrún 1974 (1974-05-30) (ọmọ ọdún 48)
Ibi ọjọ́ibíLagos, Nigeria
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
1993–1994Stationery Stores25(6)
1994–1998Al-Bourj76(13)
1998–1999BEC Tero Sasana30(5)
1999–2000Mohun Bagan16(2)
2000–2002BEC Tero Sasana58(9)
2003–2004PSPS Pekanbaru12(1)
Teams managed
2007–2009Bangkok Christian
2009Look Isan 2 (assistant)
2009–2010Thai Port (technical director)
2011Rajpracha (technical director)
2012–2016Suphanburi (director)
2017–2018Suphanburi
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of 1 September 2007.
† Appearances (Goals).

Ìgbésí ayé rẹ́Àtúnṣe

Adébáyọ̀ Gbádébọ̀ n gbé oẹ̀lú ìyàwó àti àwọn ọmọ rẹ̀ mẹ́ta.

Àwọn ìtọ́kasíÀtúnṣe

  1. "Adebayo Gbadebo". Transfermarkt (in Èdè Jámánì). Retrieved 2019-02-02.