Adebayo Ogunlesi
Adebayo "Bayo" O. Ogunlesi CON (tí a bí ni December 20, 1953) jẹ́ agbẹjọ́rò àti oní-ìdókòwò ọmọ orílẹ̀-èdè Naijiria.[1][2] Òun ni olùdarí àgbà fún Global Infrastructure Partners (GIP). Ogunlesi fìgbà kan jẹ́ olórí wọn ni Credit Suisse First Boston[3] kí wọ́n tó yàn án sípò alága.[4]
Adebayo Ogunlesi | |
---|---|
Adebayo Ogunlesi, Nigerian lawyer and investment banker | |
Ọjọ́ìbí | 20 Oṣù Kejìlá 1953 Sagamu, Ogun, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Orúkọ míràn | Bayo Ogunlesi |
Ẹ̀kọ́ | Lincoln College, Oxford Harvard Law School Harvard Business School |
Iléẹ̀kọ́ gíga | King's College, Lagos |
Iṣẹ́ | Investment banker |
Ìgbà iṣẹ́ | 1980-present |
Employer | Global Infrastructure Partners |
Olólùfẹ́ | Dr. Amelia Quist-Ogunlesi |
Àwọn ọmọ | 2 |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Sorkin, Andrew Ross (14 March 2002). "Accidental Investment Banker Shakes Up Credit Suisse Unit". The New York Times. https://www.nytimes.com/2002/03/14/business/accidental-investment-banker-shakes-up-credit-suisse-unit.html.
- ↑ Gregory, Sean (2 December 2002). "2002 Global Influentials. Adebayo Ogunlesi: CSFB's Global-Banking Chief. His Road from Nigerian Doctor's Son to Wall Street Boss Has Crossed Oil Fields, the Supreme Court and a Rifle or Two". Time. Archived from the original on 30 May 2007. https://web.archive.org/web/20070530062727/http://www.time.com/time/2002/globalinfluentials/gbiogunlesi.html. Retrieved 28 July 2023.
- ↑ McFadden, Jeanmarie; Pendleton, Pen (20 February 2002). "CSFB Names Tony James Chairman of Global Investment Banking and Private Equity". Archived from the original on 7 June 2007. Retrieved 18 May 2007. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Reed, K. Terrell (1 November 2004). "CSFB Repositions Top Exec". Black Enterprise. http://www.blackenterprise.com/mag/csfb-repositions-top-exec/.