Adebisi Mojeed Balogun (ọjọ́ìbí 2 oṣù kẹjọ odún 1952) jẹ ọmọ orílẹ-èdè Nàìjíríà onimọ ẹtọ-ògbìn biochemist, ọlukọni, onìwòsàn oúnjẹ, ọmowé atí òjògbón nípa oúnjẹ ẹ̀já, tí ọ ṣiṣẹ gẹ́gẹ́ bí ìgbákejì ọgá àgbà ilé ìwé gígá Federal University of Technology Akure láti January 2007 sí January 2012.[1][2][3]

Adebisi Balogun
Ìgbákejì kàrún tí Federal University of Technology Akure
In office
January 2007 – January 2012
AsíwájúPeter Adeniyi
Arọ́pòEmmanuel Adebayo Fashakin (acting)
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Adebisi Mojeed Balogun

2 Oṣù Kẹjọ 1952 (1952-08-02) (ọmọ ọdún 72)
Ilé-Ifẹ̀, Southern Region, British Nigeria (bayi Ìpínlẹ̀ Osun, Naijiria)
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
(Àwọn) olólùfẹ́
  • Omotola Ibiteye Olaoye
    (m. 1981, divorce)
  • Olusola Oluropo Falade
Àwọn ọmọ3
Àwọn òbíAdetunji Saka Balogun (bàbá)
Alma materUniversity of Ibadan
ProfessionOlùkọ́

Ìgbésí áyé ìbẹ̀rẹ̀ àtí ẹ̀kọ́

àtúnṣe

Adebisi Balogun ní wọn bí ní ọjọ́ kéji oṣù kẹ́jọ odún 1952 ní Ilè Ifẹ̀, nígbà náà ní Southern Region, British Nigeria, sí Adetunji Saka atí Modelola Balogun (née Afilaka). Ó lọ sí Yunifásítì ìlú Ìbàdàn níbi tí ó tí gba ẹ̀kọ́ ìmọ̀ sáyẹ́ǹsì ní 1976, ọ̀gá nínú ìmọ̀ sáyẹ́ǹsì ní 1978 àti dókítà ìmọ̀ ọ.[4]

Ìṣẹ́

àtúnṣe

Lèyìn tí ọ gba doctorate degree ní 1982, ọ dị ẹ́lẹ́gbẹ́ ìwádì, Nigerian Institute of Oceanography and Marine research, Lagos, Nigeria láti 1982 sí 1983, ọ jẹ olùkọ ní University of Ibadan láti 1983 sí 1988, ọ gbé sí Federal University of Technology Akure ní 1988. Ọ dí òjògbón ní 1994, ọ jẹ Dean tí School of Agriculture and Agricultural Technology, FUTA láti 1997 sí 2001.[4] Ọ jẹ ọmọ ẹgbẹ́ tí Alàgbà tí FUTA láti 1988 sí 2012, ọmọ ẹgbẹ́ tí ìgbìmọ̀ ìjọba láti 1993, Ìgbìmọ̀ Ìwádì Olùkọ́, Ilé-ìwé tí Agriculture atí Agricultural Technology, alága Environmental Sanitation Committee, Ìgbimọ Ìdárayá, Ìgbìmọ̀ Àwọn ayẹyẹ Alága atí Ìgbákejì Alàkóso láti Odún 2007 sí 2012.[4][3]

Àwọn ìtọkásí

àtúnṣe
  1. "Former Vice Chancellor identifies poor governance as main problem of Universities". News Diary Online. 5 August 2022. Retrieved 19 October 2022. 
  2. "Nigeria: Why Nigeria is Backwards in Technology -- Futa VC". All Africa. 23 February 2010. Retrieved 19 October 2022. 
  3. 3.0 3.1 "Previous Vice-Chancellors | FEDERAL UNIVERSITY OF TECHNOLOGY AKURE". www.futa.edu.ng. Retrieved 17 October 2022. 
  4. 4.0 4.1 4.2 "BALOGUN ADEBISI MOJEED | FEDERAL UNIVERSITY OF TECHNOLOGY AKURE" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 19 October 2022.