Adebisi Akanji (ibí 1930) jẹ́ òṣèré tí orílé èdè Nàìjíríà, bákan náà ó sí jẹ́ olóyè Olúwo Ògbóni tí ilé Ìlédì kàrún Ohùntótó, èyí tí ó jẹ́ Ògbóni tí ó jẹ́ gbóògì tí ìbílẹ̀ lodge tí ìlú Òṣogbo, ní ìpìnlẹ̀ Ọṣun ní orílé èdè Nàìjíríà.

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ Ayé àti Ìwé kíkà àtúnṣe

Ní gbà tí ó gbọ́njú, ọ ṣíṣe gẹ́gẹ́ bí Amọlé bírìkì bricklayer,[1][2] lẹyìn èyí, ó bẹ̀rẹ̀ sí ní gbé èrè láti lè gbáradì fún ìdíje èyí tí ó sí gbé àwọn ẹranko tí ó dúró fún àṣà èyí tí ó wà fún ohùn oṣo fún inú ilé ( architectural elements).[3]

Iṣé àtúnṣe

Àkànjí jẹ́ ẹnití ó gbajúmò fún iṣé àgbẹ̀dẹ̀ àti àwọn iṣé èrè. Ọ sí tún tí ṣíṣe ni ilé iṣé aṣọ[3] àwọn iṣé rẹ a máa sàlàyẹ́ àwọn ìsòrí àlọ ilé Yorùbá [Yoruba people|Yoruba]]. Ní ìbáṣepọ̀ pẹlú Susanne Wenger, ó tí ṣíṣe fún ọdún mẹwàá ní ojúbo Òṣun ní ìlú [Òṣogbo] ní orílé èdè Nàìjíríà, òun yìí náà ló gbé àwọn eré mìíràn ní ibè.[3][4]

 
Eré tí Adebisi Akanji gbé sí iwájú ìta ilé Susanna Wenger

Àwọn Ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. Jo Ann Lewis (23 January 2000), "Nigeria's 'Concrete' Achievements", Special to The Washington Post, p. G01 
  2. "Adebisi Akanji". Archived from the original on 10 July 2018. Retrieved 7 July 2015. 
  3. 3.0 3.1 3.2 "Adebisi Akanji". Retrieved 6 July 2015. 
  4. "Official Opening of the Arch of the Flying Tortoise, Osun-Osogbo, Aug. 2015 on susannewenger-aot.org". Archived from the original on 10 July 2018. Retrieved 19 June 2022. 

External links àtúnṣe


Àdàkọ:Authority control


Àdàkọ:Nigeria-artist-stub