Adebola Williams
Adebola Williams ( Abíi ní ọdún 1986) ó jẹ́ ọmọ orile-èdè Nigeria tí ó ń ṣe òwò ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́, akọ̀ròyìn, olùgbaninímọ̀ràn nípa ọ̀rọ̀ òṣèlú, àti olùsọ̀rọ̀-ìwúrí. Òun ni Olùdarí-àgbà fún ẹgbẹ́ RED | For Africa. Ó jẹ́ olùjọdásílẹ̀ àti alámòjútó Red Africa, Ilé iṣẹ́ agbóhùnsáfẹ́fẹ́ tí ó ṣe agbátẹrù àwon ọ̀dó jùlọ ní ilẹ̀ Africa ní àjọṣe pẹ̀lú Red Media Africa, Statecraft Inc., The Future Awards Africa, and YNaija.[4]
Adebola Williams | |
---|---|
Ọjọ́ ìbí | 7 Oṣù Kẹta 1986 Nigeria |
Iṣẹ́ | Journalist/media entrepreneur |
Alma mater | London School of Journalism, Pan African University |
Notable awards | Mandela Washington Fellow;[1] 100 Most Influential People of African Descent under the United Nations International Decade for People of African Descent;[2] Archbishop Desmond Tutu Fellowship in South Africa[3] |
Adebola Williams ( Abíi ní ọdún 1986) ó jẹ́ ọmọ orile-èdè Nigeria tí ó ń ṣe òwò ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́, akọ̀ròyìn, olùgbaninímọ̀ràn nípa ọ̀rọ̀ òṣèlú, àti olùsọ̀rọ̀-ìwúrí. Òun ni Olùdarí-àgbà fún ẹgbẹ́ RED | For Africa.[5] Ó jẹ́ olùjọdásílẹ̀ àti alámòjútó Red Africa, Ilé iṣẹ́ agbóhùnsáfẹ́fẹ́ tí ó ṣe agbátẹrù àwon ọ̀dó jùlọ ní ilẹ̀ Africa ní àjọṣe pẹ̀lú Red Media Africa, Statecraft Inc., The Future Awards Africa, and YNaija.[6]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Matilda Kerry, Adebola Williams, Otto Orondaam & other outstanding Young Nigerians selected for 2016 Mandela Washington Fellowship". BellaNaija. Retrieved 6 May 2016.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "Most Influential People of African Descent (MIPAD) unveils 2017 Global List". mipad.org.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "Tutu Fellows". alinstitute.org.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "Adebola Williams". World Economic Forum (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-03-18.
- ↑ "Interview: Meet The 30 Year-Old Nigerian Entrepreneur Who Helped 3 African Presidents Get Elected". Forbes. 17 February 2017. https://www.forbes.com/sites/mfonobongnsehe/2017/02/17/meet-the-30-year-old-nigerian-entrepreneur-who-helped-3-african-presidents-get-elected/.
- ↑ "The Young Moguls that built a Media Empire in Nigeria with zero capital". Tech Point. 31 October 2016. https://techpoint.ng/2016/10/31/red-media-founders-interview/.