Adefunmilayo Tejuosho
Adefunmilayo Tejuosho (orúko abiso rè ni Smith) tí a bi ní ọjọ́ karúndínlọ́gbọ̀n oṣù Kàrún ọdun 1965 jé òtòkùlú olósèlú ni Nàìjirià, o tun jé asoju agbegbe Mushin ní house of Assembly ìpinlè Eko, oun ni alaga house of assembly Eko ti o un rí si ètò owó.
Hon. Funmi Tejuosho | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Adefunmilayo Smith 25 Oṣù Kẹta 1965 ìpínlè Èkó, Nàìjíríà |
Orílẹ̀-èdè | ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà |
Orúkọ míràn | Oloori Adefunmilayo Tejuosho |
Iléẹ̀kọ́ gíga | |
Iṣẹ́ | |
Ìgbà iṣẹ́ | 1997 – present |
Political party | Ẹgbẹ́ òsèlú All Progressives Congress |
Olólùfẹ́ | Omoba Kayode Tejuosho |
Àwọn ọmọ | 4 |
Àárò Aye àti Èkó rè
àtúnṣeA bi Tejuosho ni ipinle Eko si idile Ademola Smith,[1] O lo ilé-ìwé primari ti Yunifásitì Ìlú Eko, o lo ilé-ìwé Queens College fún ìwé Sekondiri, Eko o pari ìwé Sekondiri rè ni West Virginia, léyìn ìwé rè, o tèsíwájú láti gba àmì-èye ninú ìmò Biology ni yunifásitì ti West Virginia.[2] O pada gba àmì-èye ninú imo ofin ni Yunifásitì ti Buckingham. Tenuous gba àmì-èye Ph.D nínú ìmò ofin láti Yunifásitì ti ìlú Eko.[3]
Isé rè
àtúnṣeNigba isé agubaniro rè, o sise ni ilé-ìwé Queens College ti o ti jáde. Ni odun 2003, a yan sip láti soju house of Assembly ìpinlè Eko, nigba to wa nipo náà, o mu aba ofin wa lati dojuko oko nina iyawo ati iyawo nina oko. Àbá náà pada di ofin.
Ìdílé rè
àtúnṣeO fe Omoba Kayode Tejuosho ti idile ade Tejuosho ìpínlè Ogun , Nàìjíríà.[4] awon mejeji bi omo merin.
Àwon Itokasi
àtúnṣe- ↑ Oladesu, Emmanuel (2014-05-12). "Who is next Lagos deputy governor?". The Nation Newspaper. Retrieved 2022-05-30.
- ↑ "Funmi Tejuosho" Check
|url=
value (help). Hyperleap. 1965-03-25. Retrieved 2022-05-30.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́] - ↑ "HON. FUNMI TEJUOSO LOSES FATHER". Encomium Magazine. 2022-05-30. Retrieved 2022-05-30.
- ↑ "Hon. Funmi Tejuosho enumerates what life has taught her at 49". Encomium Magazine. 2014-03-29. Retrieved 2022-05-30.