Ọọ̀ni Adegunle Adewela
(Àtúnjúwe láti Adegunle Adewela)
Adegunle Adewela ni Ọọ̀ni ẹlẹ́ẹ̀kejìlélógójì tí Ilé-Ifẹ̀ máa ní, èyí tí ń ṣe olórí ìbílẹ̀ Ilé-Ifẹ̀, tó jẹ́ orírun àwọn ọmọ Yorùbá. Lẹ́yìn tí Ọọ̀ni Wunmonije wàjà ní Ọọ̀ni Adegunle jẹ oyè yìí. Ọọ̀ni Degbinsokun ló sì jẹ oyè Ọọ̀ni lẹ́yìn tí Adegunle wàjà.[1]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Dayo, Ologundudu (2008). The cradle of Yoruba culture. Nigeria: Centre for spoken words. p. 206. ISBN 978-0615220635. https://books.google.com/books?id=Vn8uAQAAIAAJ&q=Ooni+Ojigidiri&dq=Ooni+Ojigidiri. Retrieved July 30, 2015.