Adekunle Akinlade
Oloselu Naijiria
Adekunle Akinlade (a bi Adekunle AbdulKabir Akinlade ni ojo kesan osu kewa odun 1969) je oloselu omo orile ede naijiria. O je asoju guusu Egbado ati poa ni ile igbimo asofin agba ti orile ede naijiria.[1]
O dije ipo gomina je gomina ipinle Ogun.[2]
Awon itokasi
àtúnṣe- ↑ "Adekunle Akinlade". Nigeria National Assembly. Retrieved 22 February 2019.
- ↑ "APM governorship candidate in Ogun, Akinlade, returns to APC". Premium Times Nigeria. 2019-12-23. Retrieved 2022-01-30.