Adele (Regent) ni ile kaaaro-o-jire (Yoruba) ni eni ti a yan lati dari ilu ti Oba won ba waja ti asa won kosi faye gba a pe ki ori ite Oba naa sofo. Adele a maa dari ilu ti Oba won ba n saare tabi ti ko le danto mo laaarin ilu.[1] Adele kii pe lori oye bi Oba. O maa n ni iwonba igba ti Adele maa fi n wa lori ite.[2]

Awon Itokasi

  1. "Definition of regent". www.dictionary.com. 2013-04-16. Retrieved 2019-09-23. 
  2. "REGENT - meaning in the Cambridge English Dictionary". Google. Retrieved 2019-09-23.