Ademola Adeleke

Olóṣèlú

Ademola Nurudeen Jackson Adeleke (ojoibi 13 May 1960) je oloselu ati onisowo Naijiria kan, eni ti o ti se gomina ipinle Osun lati odun 2022.[1] Òun ni Seneto tó sójú agbègbè Senatorial Osun-west lati 2017 si 2019. O wà lati ìdílé Adeleke ti Ede ni Ipinle Osun . O dije nínú idibo gomina ipinle Osun lodun 2022 labẹ ẹgbẹ oselu Peoples Democratic Party, o si bori Gómìnà to wà níbè, Adegboyega Isiaka Oyetola ti ẹgbẹ oṣelu APC ti o jáwé olubori nínú ibo gomina ipinle Osun lodun 2018 . [2]

Ademola Adeleke
10th Governor of Osun State
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
27 November 2022
DeputyKola Adewusi
AsíwájúGboyega Oyetola
Senator for Osun West
In office
2017–2019
AsíwájúIsiaka Adeleke
Arọ́pòAdelere Adeyemi Oriolowo
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Ademola Nurudeen Adeleke

13 Oṣù Kàrún 1960 (1960-05-13) (ọmọ ọdún 63)
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPeople's Democratic Party

Ẹkọ àtúnṣe

Adeleke beere ẹkọ ako bere ni Methodist Primary School, Surulere Lagos State ki o to pada Si ilu Oyo State lati tẹsiwaju ninu eko ni Nawarudeen Primary School, Ikire. Ati ile iwe ẹkọ gíga Seventh Day Adventist Secondary School, Ede ni ipinle Oyo lati ka iwe ni Ede Muslim Grammar School Ede, nibiti ti ọ ti pari secondary school education lati lọ ka iwe ni ilu United States.[3] o fi ilu Nigeria lati lọ ka ìwé pẹlu awon egbon re méjì ni United States of America.[3] iwe ẹkọ gíga ni Jacksonville State University,[4] Alabama ti ọ sí gbọye degree. nipa odaran àti oṣelu.[5]

Awon ise àtúnṣe

Ise aladani àtúnṣe

Adeleke je onisowo ati alakowe, o sise gege bii alakoso agba ni ile-ise iponti Guiness lati odun 1992 si odun 1999 nibiti ikan ninu awon akegbe re si je Oga-ogun Theophilus Danjuma;[3] o tun je alakoso agba ni ile-ise aburo re, Pacific Holdings Limited lati odun 2001 titi di odun 2016.[4] ki o to dara po mo Pacific Holdings Limited, o ti sise ni ile ise ifi nnkan ranse ti a mo si Quiksilver Courier Company ni ilu Atlanta, Georgia ni orile-ede Amerika gege bi agba ise se ni odun 1985 si odun 1989. o tesiwaju ri ile-ise awon nnkan oloorun adidun ti a mo si Origin International LLC ni ilu Atlanta ni Georgia ni orile-ede Amerika gege bi igbakeji alakoso agba patapata lati odun 1990 si odun 1994.[5]

Itokasi àtúnṣe

  1. "Gov. Ademola Nurudeen Jackson Adeleke Achievements – Osun State Official Website". Osun State Official Website – Osun – State of the Living Spring. 2023-06-12. Retrieved 2023-06-12. 
  2. "Adeleke get 17 out of 30 local goment areas to win Osun govnorship election". https://www.bbc.com/pidgin/tori-62189734. 
  3. "Ademola Adeleke's School Certificate Scandal And Other Things To Know About Osun Governor-elect | Sahara Reporters". saharareporters.com. Retrieved 2022-09-22. 
  4. "How I built multi-million dollar business in US, Senator Ademola Adeleke". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-01-19. Retrieved 2022-02-24. 
  5. Admin. "Personality of the Week: Ademola Adeleke". Sun News Online. Retrieved 27 January 2019.