Olawuyi Adenike Olayemi[1] (tí wọ́n bí ni 2 August 2004) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù alájùsáwọ̀n ti orílẹ̀-èẹ̀ Nàìjíríà fún Nigerian national team.

Adenike Olawuyi
PEAC-Pécs
Center
Personal information
Born2 August 2004
NationalityNigerian
Listed height6 ft 3 in (1.91 m)

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀

àtúnṣe

Wọ́n bí Adenike ní 2 August 2004 sí Òṣogbo, Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun.[2]

Iṣẹ́ tó yàn láàyò

àtúnṣe

Ní ọdún 2018, Adenike gba ètò ẹ̀kọ́-ọ̀fé tó tó $45,000, látàri gbígba àmì-ẹ̀yẹ fún Most Promising Player ní Olumide Oyedeji Basketball Camp, ní Ìpínlẹ̀ Èkó.[3]

Ó gbá bọ́ọ̀lù náà fún ẹgbẹ́ NKA Universitas PEAC I láti ọdụ́n 2018 wọ 2024, lẹ́yìn náà ni ó lọ sí ẹgbé NKA Universitas PEAC II ní ọdún 2024. [4]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Shehu, Idris (2023-07-18). "FULL LIST: Top players missing as Wakama unveils D'Tigress Afrobasket 2023 squad". TheCable. Retrieved 2024-03-24. 
  2. Reporters, Our (2023-08-11). "Adeleke receives D'Tigress star Olawuyi". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2024-03-23. 
  3. The Eagle Online (2018-09-05). "Oyedeji camp: Teenage sensations bag $45,000 scholarships". The Eagle Online. Retrieved 2024-03-24. 
  4. "Adenike Olawuyi, Basketball Player, News, Stats". Eurobasket LLC. 2023-12-03. Retrieved 2024-03-24.