Adeola Adijat Faleye (ọjọ́ìbí October 10, 1968) jẹ́ olùkọ́ ní Ẹ̀ka-ẹ̀kọ́ Imọ̀-èdè àti Litirésọ̀ Áfríkà ní Obafemi Awolowo University. Litireso apohun ni o ni ife si ju lo, ibe si ni pupo ninu awon ise re da le lori. Sasa ni ohun ti ko le pe, ijala ni o, alamo ni o, esa eegun ni o, gbogbo re ni o le pe daadaa.