Adetola Salau(Abi ni June 24, 1977) òjé Olukọ pẹlu Oloselu Ọmọ bíbí orilede Naijiria osi je olubadamoran pataki nípa ètò ẹkọ sí ijoba Kwara State.

Dr
Adetola Salau
Ọjọ́ìbí24 Oṣù Kẹfà 1977 (1977-06-24) (ọmọ ọdún 47)
Elizabeth, New Jersey, United States
Orílẹ̀-èdèNigerian
Orúkọ mírànAriyike
Iléẹ̀kọ́ gíga
EmployerKwara State Government
TitleDr

Oti fi igba kan je Olubadamoran Pataki Si Gómìnà ìpínlẹ̀ Èkó Laarin 2020-2023.

Igbeaye Ati Eko

àtúnṣe

In Elizabeth, New Jersey|Elizabeth, New Jersey, Ni wọn ti bi Adetola Salau fún Salau Ademola and Oreoluwa. Ọmọ Ifelodun, Kwara|Ifelodun LGA in Kwara State, ti ori run re je Offa, Nigeria|Offa local government in Kwara south.[1][2]

O Gbọye Degree Ni Chemistry Ni Ile-eko Gíga Fordham University]] Ni Ọdún 1998, àti Syracuse University fun Ẹkọ Master Degrees Ni Engineering Management (2001) and Chemical Engineering (2004). O Parí ekó Doctorate in Curriculum, Instruction and the Science of Learning No State University of New York at Buffalo.[3]

Adetola ni Olùdámọ̀ràn pàtàkì sí Gomina Kwara Lori Eto Ẹkọ.[4]

Ọkan lára àwọn Olùkọ Adjunct lecturer|Adjunct Lecturer ni Fordham University South Carolina and North Carolina

Oje Olùdásílẹ̀ Carisma4U Educational Foundation, mathematics|STEM subjects as critical tools for improving lives and driving development.[5]

Amin ẹyẹ Sphere Woman of the Month: Adetola Salau by Princewill Ohaji July 6, 2021.[6]

Award 100 top Career women in Africa[7]

Publications

àtúnṣe

Transforming learning through relevant STEM education for Nigerian students : (Work in Progress by the Social Innovation Enterprise; Carisma4U Educational Foundation)[8]

References

àtúnṣe

Àdàkọ:Draft categories