Adewale Maja-Pearce
Oníwé-Ìròyín
Adewale Maja-Pearce (tí a bí ní ọdún 1953) jẹ́ òǹkọ̀wé, akọ̀ròyìn àti lámèyítọ́, tó gbajúgbajà fún àwọn àròkọ rẹ̀. Ó ti kọ ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìwé, bíi My Father's Country ní Ọdún 1987 àti The House My Father Built ní ọdún 2014, àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìwé onítàn.
Adewale Maja-Pearce | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 1953 (ọmọ ọdún 70–71) London, England |
Ẹ̀kọ́ | St. Gregory's College, Lagos |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University College of Wales; SOAS University of London |
Iṣẹ́ | Writer, journalist and literary critic |
Website | Àdàkọ:Website |
Ìbẹ̀ẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeAdewale Maja-Pearce ní a bí ní Ilu Lọndọnu, England, sínú ìdílé kan tí wọ́n jẹ́ ọmọ Gẹ̀ẹ́sí àti Yorùbá. Ó dàgbà sí Ìpínlẹ̀ Èkó, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ó lọ sí ilé-ìwé St. Gregory, ní Obalende, láti ọdún 1965 wọ 1969.[1] Ó sì padà lọ sí ìlú Britain láti kẹ́kọ̀ọ́ si ní University College of Wales, ní ìlú Swansea (BA, 1972–75), ó sì tún lọ sí School of Oriental and African Studies, tó jẹh London University (1984-86), níbi tí ó ti gboyè Masters nínú ẹ̀kọ́ ìmọ̀ nípa Africa. [2]
Ìwé àkọsílẹ̀
àtúnṣe- Ni Orilẹ-ede Baba Mi: Irin-ajo Nàìjíríà (William Heinemann, 1987), CreateSpace Independent Publishing Platform, 2011,ISBN 978-1467913973 .
- Ibusọ melo ni si Babiloni? Aroko Heinemann, Ọdun 1990,ISBN 978-0434441723 .
- Jijo boju-boju: Awọn onkọwe ara ilu Naijiria ti awọn ọgọrin, Hans Zell Publishers, 1992.ISBN 978-0905450926ISBN 978-0905450926 .
- Lati Khaki si Agbada: Iwe afọwọkọ fun awọn idibo Kínní, 1999 ni Nigeria, Ẹgbẹ Ominira Ilu, 1999,ISBN 978-9783218895 .
- Ranti Ken Saro-Wiwa ati Awọn arosọ miiran, Gong Tuntun, 2005,ISBN 978-9783842106 .
- Ibanujẹ Pataki: JP Clark-Bekederemo ati Ibẹrẹ ti Awọn iwe-kikọ Naijiria ti ode oni ni Gẹẹsi, CreateSpace Independent Publishing Platform, 2013,ISBN 978-1492184553 .
- Ile ti Baba Mi Kọ, Kachifo Limited, 2014,ISBN 978-9785284218 .
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Adewale Maja-Pearce at LinkedIn.
- ↑ Adewale Maja-Pearce page, Amazon.