Adewale Oluwatayo (1950–2016) je omo ile ìgbìmọ̀ aṣòfin to n sójú àgbègbè Ifako-Ijaye. Ó sìn gẹ́gẹ́ bí alága ìjọba ìbílẹ̀ Ifako-Ijaiye láàárín ọdún 2004 sí ọdún 2007. O je oludamoran pàtàki lórí ètò ẹ̀kọ́ fún ìjọba ìpínlè Eko làti ọdun 2009 si 2011. [1]

Igbesi aye ibẹrẹ ati ẹkọ

àtúnṣe

Awọn itọkasi

àtúnṣe