Adeyemi Afolahan

Olóṣèlú

Adeyemi Afolahan (bíi Ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n Oṣù kejìlá Ọdún 1947) jẹ́ alábójútó àkọ́kọ́ ìpínlẹ̀ Taraba, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Wọ́n yàán ní ọdún 1991 lẹ́yìn ìgbà tí wọ́n dá ìpínlẹ̀ Taraba sílẹ̀.[1][2][3]

Adeyemi Ambrose Afolahan
Alábójútó àkọ́kọ́ ìpínlẹ̀ Taraba
In office
Ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n Oṣù kẹjọ Ọdún 1991 – Ọjọ́ kejì Oṣ̀ù kínín Ọdún 1992
AsíwájúAbubakar Salihu (Gongola State)
Arọ́pòJolly Nyame
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí26 Oṣù Kejìlá 1949 (1949-12-26) (ọmọ ọdún 74)
Ibadan, Oyo State, Nigeria

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Nigerian States". WorldStatesmen. Archived from the original on 28 May 2010. Retrieved 2010-05-28. 
  2. Pita Ochai and Gift Uwaezuoke (6 December 2009). "In the News". Archived from the original on 2012-02-27. Retrieved 2010-05-28. 
  3. Mathias Oko (30 May 2000). "Navy top brass joins in the campaign against AIDS". Newswatch. Retrieved 2010-05-28.