Adijat Gbadamosi Jẹ́ abẹṣẹku-bi-ojo nínú ìpele bantamweight, ó sì gba àmi ẹ̀yẹ fàdákà nínú ìdíje òlíḿpíkì tí àwọn ọ̀dọ́ ni Buenos Aires ọdún 2018. Ó jẹ́ ọmọbìnrin àkọ́kọ́ tí yóò gba oyè ẹni aláwọ̀ dúdú tí ó mọ ẹsẹ̀ jà jùlọ lẹ́hìn ìgbà tí ó jáwé olúborí lórí ọmọ orílẹ̀ èdè Zimbabwe Patience Mastara nínú ìdíje náà [1].[2][3][4]

Adijat Gbadamosi

Adijat Gbadamosi, Wọ́n bí ni ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n, oṣù Kejìlá, ọdún 2001 ní Orílẹ̀-èdè Nigeria.

Adijat Gbadamosi bẹ̀rẹ̀ eré ẹ̀ṣẹ́ kíkàn rẹ̀ fún kíkópa nínú àwọn ìdíje tí ẹsẹ̀ kùkú, kí ó tó di pé ó sojú Nàìjíríà ní ọdún 2018 nínú ìdíje Olimpiki àwọn ọ̀dọ́ tí ó wáyé ni Buenos Aires ní ìlú Argentina, tí ó sì gba àmì ẹ̀yẹ fàdákà léhìn ìgbà tí ó pàdánù sí owó ìkejì rẹ̀, arábìnrin ọmọ ilẹ̀ Italy, Martina La Piana. [5]

[6] [7]

[8][9]Ní ọdún kan náà, ó gba àmì ẹ̀yẹ Wúrà nínú ìdíje African Youth Boxing Championship ní ìlú Morocco. Ní ọdún 2019, Gbadamosi gba àmì ẹ̀yẹ ẹni tí ó mọ ẹ̀ṣẹ jà jùlọ, tí ọ̀kànlélọ́gọ́rùn-ún irú rẹ̀, tí ó máa ń wáyé ní ọjọ́ Sátisé tí ó ń gbéyìn oṣù. Tí ó wáyé ní ibi ìṣeré Mobolaji Johnson, ìlú Èkó.


[6]

Adijat Gbadamosi
Statistics
NationalityNigerian
Birth dateDecember 31, 2001
Boxing record
Wins by KO1
  1. The Nation, Nation (2019-04-19). "Adijat Gbadamosi shines". The Nation. https://thenationonlineng.net/adijat-gbadamosi-shines/. 
  2. Sports, Pulse (2023-06-22). "Nigeria's Adijat Gbadamosi makes history as she wins ABU Title at 'King of the Ring 3'". Pulse Sports Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-10-25. 
  3. Agbede, Wale (2023-06-29). "Nigeria's first female professional boxing champion Adijat Gbadamosi pushes for world title". Peoples Gazette (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-10-25. 
  4. Eludini, Tunde (2023-07-02). "Adijat Gbadamosi: New African boxing queen sets sights on world title". Premium Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-10-25. 
  5. Agbaje Samson
  6. "Italy's Martina La Piana puts her father through the ringer". IBA (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-10-17. Retrieved 2023-03-12. 
  7. Ogunseye, Adebanjo (2018-10-22). "Boxing Sensation Gbadamosi says Youth Olympic Silver Medal is Consolation". Latest Sports News In Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-03-12. 
  8. The Nation, Nation (2019-04-19). "Adijat Gbadamosi shines". The Nation. https://thenationonlineng.net/adijat-gbadamosi-shines/. 
  9. "WBO bout tops King of The Ring contest". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-12-12. Retrieved 2023-03-12.