Adil (Adel) Abdul-Mahdi (al Muntafiki) (Lárúbáwá: عادل عبد المهدى‎ ) (ojoibi 1942 ni Baghdad, Iraq) je Shi'a oloselu, onimo oro-okowo ati ikan ninu awon Igbakeji Aare ile Irak meji tele. Teletele o ti je Alakoso Eto Inawo ninu ijoba igbadie.

Adil Abdul-Mahdi
عادل عبد المهدي
Adil Abdul-Mahdi in 2008
Prime Minister of Iraq
In office
25 October 2018[1] – 7 May 2020
ÀàrẹBarham Salih
DeputyThamir Ghadhban
Fuad Hussein
AsíwájúHaider al-Abadi
Arọ́pòMustafa Al-Kadhimi
Minister of Oil
In office
8 September 2014 – 19 July 2016
Alákóso ÀgbàHaider al-Abadi
AsíwájúAbdul Karim Luaibi
Arọ́pòJabbar Alluaibi
Vice President of Iraq
In office
7 April 2005 – 11 July 2011
Serving with Ghazi al-Yawer (until 2006) and Tariq al-Hashimi (after 2006)
ÀàrẹJalal Talabani
AsíwájúRowsch Shaways
Arọ́pòTariq al-Hashimi
Minister of Finance
In office
2 June 2004 – 6 April 2005
Alákóso ÀgbàAyad Allawi
AsíwájúKamel al-Kilani
Arọ́pòAli Allawi
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Adil Abdul-Mahdi al-Muntafiki

1 Oṣù Kínní 1942 (1942-01-01) (ọmọ ọdún 82)
Baghdad, Kingdom of Iraq
Ẹgbẹ́ olóṣèlúIndependent (since 2017)[2]
SIIC (1982–2017)[3]
Iraqi Communist (1970s)[4]
(Àwọn) olólùfẹ́Rajah
Alma materUniversity of Baghdad(BA)
University of Poitiers (MA, PhD)

Ìgbẹ́ ayé rẹ̀ àtúnṣe

Wọ́n bí Adil ní ìlú Baghdad ní ọdún 1942. Ó kẹ́kọ́ ní Baghdad College. Ó kẹ́kọ́ nípa ìmọ̀ Economics ní fasiti Baghdad. Adil ṣiṣẹ́ gẹgẹ bí akọ̀wé fun Iraqi foreign Ministry ni ọdún 1965. Ni ọdún 1972, o keko gboye Masters ni fasiti University of Poitiers.

Ikọwe fiposile àtúnṣe

Ni ojo kokandinlogbon, oṣù kọkànlá ọdún 2019, leyin ọpọlọpọ ifehonuhan, Mahdi sọpé ohun kowe fiposilẹ.[5][6] Aṣòfin Iraqi fọwọ́sí ikowe fiposilẹ rẹ ni ọjọ́ kinni, oṣù Kejìlá ọdún, 2019.



Itokasi àtúnṣe