Àdìsá Akinloyè

Olóṣèlú
(Àtúnjúwe láti Adisa Akinloye)

Augustus Meredith Àdìsá Akinloyè (August 19, 1916 – September 18, 2007) jẹ́ olóṣèlú ọmọ ilẹ̀ Naijiria.

Àdìsá Akinloyè
Ọjọ́ìbí(1916-08-19)Oṣù Kẹjọ 19, 1916
AláìsíSeptember 18, 2007(2007-09-18) (ọmọ ọdún 91)
Orílẹ̀-èdèNaijiria
Iṣẹ́Agbejoro
Oloselu
Gbajúmọ̀ fúnGege bi alaga egbe oselu NPN