Adjetey Anang (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹjọ oṣù keje ọdún 1973) jẹ́ òṣèrékùnrin ti orílẹ̀-èdè Ghana tí ọ̀pọ̀ ènìyàn mọ̀ sí "Pusher", èyí tó jẹ́ ẹ̀dá-ìtàn tó ṣe nínú fíìmù Things We Do for Love.[1][2] Ó ti ṣàfihàn nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ fíìmù ilẹ̀ Ghana, lára wọn ni Deadly Voyage, A Sting in a Tale, The Perfect Picture àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Bẹ́ẹ̀ sì ni ó ti farahàn nínú fíìmù ilè German kan, tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Slavery.[3]

Adjetey Anang
Ọjọ́ìbíAdjetey Anang
7 Oṣù Keje 1973 (1973-07-07) (ọmọ ọdún 51)
Orúkọ mírànPusher
Ẹ̀kọ́Fine Arts, University of Ghana
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity of Ghana
Iṣẹ́Actor
Gbajúmọ̀ fúnDeadly voyage, A string in a Tale, The perfect picture, Slavery, Double cross, Sugar
Olólùfẹ́Elorm Anang
Àwọn ọmọ1
Awards2022 Exclusive men of the year Africa awards Actor of the year,Ghana Union of Theatre Societies (GUTS) Best actor award

Ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀

àtúnṣe

Adjetey Anang kẹ́kọ̀ọ́ gboyè ní Labone Senior High School, kí ó tó lọ sí University of Ghana, láti lo kẹ́kọ̀ọ́ nípa Fine Arts. Ó tẹ̀síwájú láti lọ kẹ́kọ̀ọ́ nípa Dramatic Arts ní Wits University, níJohannesburg.[4]

Iṣẹ́ rẹ̀

àtúnṣe

Anang ti farahàn ní fíìmù ilẹ̀ Ghana tí àkọ́lé rẹ̀ jé Yolo èyí tó gba àwọn ọ̀dọ́ níyànjú.[5]

Anang jẹ́ ọ̀kan lára àwọn òṣèré tí wọ́n yàn fún àmì-ẹ̀yẹ ní 2023 Africa Magic Viewers' Choice Awards.[6]

Àwọn ìwé àkọsílẹ̀ rẹ̀

àtúnṣe

Ní oṣù keje ọdún 2023, ó ṣe àtẹ̀jáde ìwé rẹ, tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́: ‘Adjetey Anang: A Story of Faith, Imperfection and Resilience’. Ìwé náà sọ nípa ìrírí rẹ̀ láti ìgbà èwe rẹ̀, títí tí ó fi di ìlú-mọ̀ọ́ká nínú iṣẹ́ rẹ̀.[7][8] Àtẹ̀jáde ìwé náà wáyé nígbà ayẹyẹ ọjọ́-ìbí àádọ́ta ọdún rẹ̀.[9]

Àwọn fíìmù rẹ̀

àtúnṣe

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Be Bold And Declare Your Spouse, Adjetey Anang". Peace FM online. http://www.peacefmonline.com/pages/showbiz/news/201409/214376.php. 
  2. Tetteh, O. (2020-05-27). "Adjetey Anang shares photo of his all-grown-up son who looks just like him". Yen.com.gh - Ghana news. (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-02-27. 
  3. "Exclusive Interview With Adjetey "Pusher" Anang". modernghana.com. Retrieved 27 August 2013. 
  4. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named AA2
  5. Ayub, Simon (2020-06-23). "A comprehensive overview of YOLO cast: names, images". Yen.com.gh - Ghana news. (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-02-27. 
  6. "AMVCA 2023: And The Big Nominees Are…". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2023-04-22. Retrieved 2023-04-23. 
  7. Dadzie, Kwame (Jul 10, 2023). "I initiated flirtatious conversations and led many women on – Adjetey Anang". Myjoyonline. 
  8. ""I have cheated on my wife many times" – Adjetey Anang confesses in new book". Citinewsroom - Comprehensive News in Ghana (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2023-07-10. Retrieved 2023-08-31. 
  9. Johnson, Reymond Awusei (2023-07-09). "Adjetey Anang launches book as he clocks 50". Pulse Ghana (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-08-31. 
  10. "LIFE AND LIVING IT". Talk African Movies (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2013-09-13. Retrieved 2021-03-06. 
  11. The Perfect Picture, retrieved 2018-11-20 
  12. "'The Perfect Picture' breaks new ground in Ghanaian Cinema - BellaNaija". www.bellanaija.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 6 April 2009. Retrieved 2018-11-20. 
  13. "The Perfect Picture | African Film". africa-archive.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2018-11-20. 
  14. A Sting in a Tale, retrieved 2018-11-20 
  15. Potomanto, retrieved 2018-11-20 
  16. Double-Cross, retrieved 2018-11-20 
  17. Devil in the Detail, retrieved 2018-11-20 
  18. "Sparrow Productions bounces back with 'Four Big Things' - MyJoyOnline.com". www.myjoyonline.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-02-03. 
  19. ""My Very Ghanaian Wedding" to hit Screens soon | News Ghana". Ghana News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-02-20. 
  20. Potato Potahto, retrieved 2018-11-20 
  21. "Shirley Frimpong-Manso's 'Potato Potahto' makes it to Netflix - MyJoyOnline.com". www.myjoyonline.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-02-03. 
  22. Keteke, retrieved 2018-11-20 
  23. Sidechic Gang, retrieved 2018-11-20 
  24. "Yvonne Nelson premieres Sin City on Val's Day". 14 January 2019. 
  25. Gold Coast Lounge (2020) - IMDb, retrieved 2021-03-06