Admiralty Circle plaza wa ni ijoba ibile Eti-Osa ni Ipinle Eko ni Nàìjíríà . A dasilẹ lati gba owó ní ònà Lekki-Eti-Osa expressway, ònà tí o to kilometer kandinlogota(49km)  Kíko plaza náà jẹ adehun laarin ijọba ipinlẹ Eko ati Messrs ikeja Concession Company Limited LCC.[1] Iṣẹ bẹrẹ ni plaza ni ọjọ 5 Oṣu Kini(5 January), ọdun 2011.[2]

Admiralty Circle Plaza

Awọn itọkasi àtúnṣe

  1. Eribake, Akintayo (December 15, 2011). "Tension as Lagos govt insists on toll collection". Vanguard News. Retrieved September 12, 2022. 
  2. "Admiralty Circle Plaza Archives - P.M. News". PM News Nigeria. September 12, 2022. Retrieved September 12, 2022.