Ado Gwanja

Olórin àti òṣèrékùnrin ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà

Ado Isah Gwanja (tí wọ́n bí ní 22 January 1990) jẹ́ olórin ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, àti òṣèrékùnrin nínú àwọn fíìmù àgbéléwò ti apa Gúúsù ilẹ̀ Nàìjíríà.[2][3]

Ado Gwanja
Ado Isah Gwanja
Ọjọ́ìbíAdo Isah Gwanja
22 Oṣù Kínní 1990 (1990-01-22) (ọmọ ọdún 34)
Kano
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigeria
Iléẹ̀kọ́ gígaFederal College of Education Kano
Iṣẹ́Singer, Film Producer and Film Actor
Ìgbà iṣẹ́2017-Present
Gbajúmọ̀ fúnMusicians
Àwọn ọmọ1 daughter[1]
AwardsGet Kano award Best Actor, Sani Abacha Youth Center Award Best Hausa artists Rhymes Pillars Crew

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Ado Gwanja na cikin wasa a Legas aka shaida masa matarsa ta haihu". 22 August 2019. 
  2. "Ni ba dan daudu ba ne – Ado Gwanja". BBC News Hausa (in Èdè Hausa). 18 November 2021. Retrieved 27 April 2022. 
  3. Admin (14 March 2022). "CIKAKKEN TARIHIN ADO GWANJA - Northernwiki Mawaka". Northernwiki (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 19 May 2023. Retrieved 24 April 2022.