Adowa smart

Òṣèrébìnrin ilẹ̀ Ghana

Belinda Naa Ode Oku (tí wọ́n bí ní ọjọ́ Kàrún oṣù kẹwàá ọdún 1970) jẹ́ òṣẹ̀rébìnrin ilẹ̀ Ghana tí ọ̀pọl ènìyàn mọ̀ sí "Adwoa Smart". Wọ́n bí i sí ìlú Abossey Okai, ní ìgbèríko Accra ní ìlú Ghana. Adwoa tí kópa nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ fíìmù, bẹ́è sì ni ó ti kópa nínú fọ́nrán orin lóríṣiríṣi. Adwoa bọ́ sí gbàgede lẹ́yìn tí ó kópa nínú fíìmù "Obra" (Life) èyí tí wọ́n ṣàfihàn ní orí GTV.[1]

Adowa smart
Ọjọ́ìbíBelinda Naa Ode Oku
5 Oṣù Kẹ̀wá 1970 (1970-10-05) (ọmọ ọdún 54)
Accra
Orílẹ̀-èdèGhanaian
Orúkọ mírànAdwoa Smart
Iṣẹ́Actress
Gbajúmọ̀ fúnObra, Efie Wura, Yaa Asantewa, Money bag , Father and Son
Parents
  • Mr Oku (father)
  • Mrs. Oku (mother)

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Belinda Naa Ode Oku, Adwoa Smart". www.ghanaweb.com. Retrieved 2019-06-29.