Adunni Bankole
Adunni Bankole (Oṣù Kẹ́tá, ọdún 1959 - ọjọ́ Kẹ́tá Oṣu Kini ọdún 2015) jẹ ólùdarí àwùjọ ni Nàijíríà atí óbinrín oníṣòwò. Ó jẹ́ Yèyé Mokun tí ijọ́bá Owu, ìlú kan ni Abẹ́òkúta, olú-ìlú ti Ìpínlẹ̀ Ògùn, gúusù ìwọ̀-óòrùn Nàijíríà .
Adunni Bankole | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | March 1959 Abeokuta, Ogun State, Nigeria |
Aláìsí | 3 January 2015 |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Orúkọ míràn | Yeye Mokun of Owu kingdom[1] |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ | Businesswoman |
Olólùfẹ́ | Alani Bankole[2][3] |
Àwọn olùbátan | Dimeji Bankole (Step son)[4] |
Ìgbésí ayé
àtúnṣeA bi ní Oṣù Kẹ́tá ọdún 1959 ni Owu ti Abẹ́òkúta ni Ìpínlẹ̀ Ògùn, gúusù ìwọ̀-óòrùn Nàijíríà . Ó ṣe ìgbéyàwó pẹlú olóṣèlú ijọ́bá olómìníraá kejí, Olóyè Alani Bankole tí ó jẹ́ baba fún agbọ̀rọ̀sọ tẹ́lẹ̀ tí ilé àwọn aṣojú, ọlọla Dimeji Bankole .
Iku
àtúnṣeO kú nípa ìkọlù ọkàn ní ọjọ́ Kẹ́tá Oṣù Kiní ọdún 2015 lẹ́yìn iṣẹ́ abẹ ọkàn. Ìròyìn wípé ó kú ní wákàtí diẹ̀ ṣáajú ayeye ìgbéyàwó ti ọmọbirin rẹ̀.[5][6]
Wo eléyì na
àtúnṣeÀwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Society lady, Mrs Adunni Bankole dies on daughter's wedding day". Linda Ikeji's Blog. January 3, 2015. Retrieved May 24, 2022.
- ↑ Akinwale, Funsho (January 3, 2015). "Iyalode Adunni Bankole dies on daughter's wedding day -". The Eagle Online. Retrieved May 24, 2022.
- ↑ Dede, Steve (January 5, 2015). "Lagos socialite, Adunni Bankole, dies on daughter’s wedding day". Pulse Nigeria. Archived from the original on February 8, 2020. Retrieved May 24, 2022.
- ↑ Citizen, The (January 4, 2015). "Adunni Bankole dies on daughter's wedding day". Nigerian Voice. Retrieved May 24, 2022.
- ↑ "Bankole loses step-mother on daughter’s wedding day". Vanguard News. January 3, 2015. Retrieved May 24, 2022.
- ↑ "Society Lady, Adunni Bankole, is Dead, Articles - THISDAY LIVE". thisdaylive.com. January 19, 2015. Archived from the original on January 19, 2015. Retrieved May 24, 2022. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)