Ìgbòdì oúnjẹ
(Àtúnjúwe láti Adverse food reaction)
Ìgbòdì oúnjẹ jẹ́ ìgbòdì ara sí oúnjẹ tàbí sí oúnjẹ kan pàtó.[1] Ìgbòdì tí ó wọ́pọ̀ jùlọ ni ẹhùn oúnjẹ, tí ó jẹ́ ìlòdì ara sí yálà sí ounjẹ kan pàtó tàbí oríṣiríṣi protein oúnjẹ. Síbẹ̀síbẹ̀, àwọn ìlòdi ara sí oúnjẹ míràn kìí ṣe àwọn ẹhùn.