Afẹ Babalọla
Afẹ Babalọla CON OFR SAN (Wọn bíni ọjọ ọgbọn, oṣu October, ọdún 1929) jẹ agbẹjọro ilẹ [Naijiria] ati oludasilẹ ilé ìwé gíga ti Afẹ Babalọla[1][2][3].
Afe Babalola CON Order of the Federal Republic | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 30 Oṣù Kẹ̀wá 1929 Ado Ekiti, Southern Region, British Nigeria (now in Ekiti State, Nigeria) |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 1963–Present |
Àwọn olùbátan | Bolanle Austen-Peters (daughter) |
Awards |
|
Website | afebabalola.com |
Ìgbésí ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeAfẹ́ Babalọlá ni à bisi ipinlẹ Ekiti ni gúúsù ìwọ oòrùn ilẹ̀ Naijiria. Arákùnrin náa lọ sí ilé ìwé akọbẹẹrẹ Emmanuel ni Ado-Ekiti[4]. Lẹ́yìn náà lọ gba ìwé ẹri ilé ìwé Cambridge níbi to ti kàwé ni alabagbe pọ Wolsey, Oxford. Leyin náà lo gba iwe ẹri ti A'level kòtò dipe ó lọ sí ilé ìwé london níbi tó ti gboye lórí imọ ọrọ aje[5][6][7].
Arákùnrin náà ṣíṣe fún ìgbà díẹ̀ ni ile ìwé ifowopamọ àpapọ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà kò tó di pé ó lọ sí ilé ìwé gíga London láti gboyè ni imọ òfin[8]. Ní ọdún 1963, wọn pé sì bar tí England, ọdún náà lo di ọkàn lára àwọn ọmọ ẹgbẹ Lincoln Inn ni ilu London.
Babalọla fẹ arábìnrin Modupẹ Mercy Babalọla ti wọn si bímọ mẹsan lára wọn ni Bolanle Austen-Peters[9].
Isẹ Afẹ Babalọla gẹ́gẹ́bí Amofin
àtúnṣeAfẹ Babalọla bẹ̀rẹ̀ ìṣẹ rẹ ni ìlú Ibadan, èyí jẹ olú ìlú ipinlẹ Ọyọ, ìwọ oorun ilẹ̀ Nàìjíríà gẹ́gẹ́bí oludajọ ẹni tí a fẹ́ sunkan ni ile iṣẹ Olú Ayọọla àti Co[10]. Lẹ́yìn ọdún méjì ni iṣẹ adajọ lo dá ilé ìṣẹ idajọ tí ẹ silẹ Afẹ Babalọla Àti Co[11]. Ní ọdún 1987, arákùnrin náà di Alagba wí àgbà tí ilẹ Naijiria (SAN) , èyí jẹ ìṣẹ idajọ tó ga julọ[12].
Ní ọdún 2009, arákùnrin náà dá ilé ìwé gíga Afẹ Babalọla sílè ni ọna láti gbé eto ẹkọ lárugẹ ni ilẹ Naijiria. Ní ọdún 2013, ilẹ ìwé náà jẹ ti aladani tó dáraju ni ipò ẹlẹkeji ni Naijiria[13].
Ní ọdún 2002, Afẹ Babalọla darapọ mọ ẹgbẹ́ idasilẹ àwọn oludajọ ilẹ Naijiria to sì jẹ Arẹ fún idasilẹ náà láti ọdún 2017 de October, 2021. Arákùnrin náà ṣíṣe takuntakun nígbà ìdarí rẹ ni idasilẹ náà to jẹ pé lẹ́yìn tó fẹyinti ó jẹ olutilẹyin NICArb àti ADR[14].
Àwọn Itọkasi
àtúnṣe- ↑ "Afe Babalola biography, net worth, age, family, contact & picture". Nigeria Business Directory - Find Companies, People & Places in Nigeria. 1929-10-30. Retrieved 2023-10-04.
- ↑ Jacobs, Juwon (2015-07-13). "That Afe Babalola University May Truly Excel, Articles". thisdaylive.com. Archived from the original on 2015-07-13. Retrieved 2023-10-04.
- ↑ "Aare Afe Babalola reacts to Omirin, APC lawmakers threat to shun peace meeting". Daily Post Nigeria. 2015-04-30. Retrieved 2023-10-04.
- ↑ Ifeoma, Peters (2017-10-02). "Legal Luminary Profile: Aare Emmanuel Afe Babalola, SAN, CON, OFR -". - Blazing The Trails, Providing World Class Legal Services. Archived from the original on 2020-10-26. Retrieved 2023-10-04.
- ↑ "A living legend: Afe Babalola". The Nation Newspaper. 2017-10-28. Retrieved 2023-10-04.
- ↑ "I want to live beyond 114 years – Afe Babalola". The Punch - Nigeria's Most Widely Read Newspaper. 2011-02-23. Archived from the original on 2013-11-28. Retrieved 2023-10-04.
- ↑ "Between Obafemi Awolowo and Afe Babalola - The Nation". The Nation. 2015-05-23. Archived from the original on 2015-07-07. Retrieved 2023-10-04.
- ↑ Olatunji, Daud (2011-02-23). "At 80, Babalola teaches law at ABUAD". The Punch - Nigeria's Most Widely Read Newspaper. Archived from the original on 2015-02-18. Retrieved 2023-10-04.
- ↑ "Yeye Aare Modupe Babalola,FSM,FNIMN". Afe Babalola University. 2017-03-03. Archived from the original on 2023-10-07. Retrieved 2023-10-04.
- ↑ Bankole, Idowu (2022-05-20). "[Vanguard Awards] Afe Babalola: A lifetime of achievements". Vanguard News. Retrieved 2023-10-04.
- ↑ Nigeria, Guardian (2015-03-11). "Lessons Learnt From Celebrating Aare Afe Babalola". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. Archived from the original on 2016-05-13. Retrieved 2023-10-04.
- ↑ "Babalola bags University of London LLD". sunnewsonline.com. 2015-02-22. Archived from the original on 2015-08-01. Retrieved 2023-10-04.
- ↑ "Former minister, others applaud ABUAD’s law programme". The Punch - Nigeria's Most Widely Read Newspaper. 2011-02-23. Archived from the original on 2015-02-19. Retrieved 2023-10-04.
- ↑ Nigeria, Guardian (2021-10-12). "NICArb elects Ajogwu as president". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. Archived from the original on 2023-04-30. Retrieved 2023-10-04.