Ọdún Afan jé ayẹyẹ ọdọọdún tí wọ́n máa ń ṣe ní gbogbo ọjọ́ kìíní oṣú kìíní. Àwọn Oegworok, tí wọ́n wá láti apá Gúúsù ilẹ̀ Kaduna, ní Nàìjíríà.[1] Á ti tó ọ̀ọ́dúnrun ọdún tí wọ́n ti í ṣe é bọ̀. [2] Ayẹyẹ náà máa ń wáyé ní gbogbo ọjọ́ kìíní, oṣù kìíní, ní ààfin olóyè Kagoro ní ìjọba ìpínlẹ̀ Kaura.[3]

Afan National Festival
Bwok A̠fan
Agworok hunters marching at the Afan National Festival, 2020 edition
StatusActive
GenreFestivals
FrequencyAnnually
VenueChief's Palace Square
Location(s)Ucyio, Kagoro, Kaduna State
Coordinates9°36′N 8°23′E / 9.600°N 8.383°E / 9.600; 8.383Coordinates: 9°36′N 8°23′E / 9.600°N 8.383°E / 9.600; 8.383
CountryNigeria
Years activec. 1500 - Present
FounderA̠nkwai clan
Previous eventJanuary 1, 2020
Next eventJanuary 1, 2021
ParticipantsOpen to the world
Activity• Hunting charade
• Cultural displays (dances, songs)
• March pasts
• Award presentation
• Special prayers for the land
Patron(s)Chief of Kagoro
Organised byKagoro Development Association (KDA)
PeopleOegworok people
The Gworok (Kagoro) Hills

Wúnrẹ̀n náà "Afan" túnmọ̀ sí "orí-òkè". Ní ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀, àwọn èèyàn Afan máa ń gbé lórí àpáta àti inú ihò àpáta.[4][5][6][7]

 
Agworok hunters marching alongside participants of the festival across the town at Agban District in the 2020 Edition.

Kí ìgbà ọ̀làjú tó dé

àtúnṣe

Nínú àṣà wọn, ọdún Afan máa ń tọ́ka ìparí ọdún ìkórè kan fún ọdún náà.[3][6] Gẹ́gẹ́ bí Achi ṣe sọ nínú Achi et Al (2019), ayẹyẹ Afan náà tí àwọn Agworok máa ń ṣe jẹ́ èyí tí wọ́n máa ń ṣe ní ọjọ́ àbámẹ́ta tó ṣìkejì nínú oṣù kẹrin lọ́dọọdún. Wọn ò mọ ọdún tí ayẹyẹ yìí bẹ̀rẹ̀ n í pàtó àmọ́, wọ́n gbàgbọ́ pé ayẹyẹ náà kọ́kọ́ wáyé ní 1500 A.D.[6]

 
An Agworok traditional medicine woman at the Afan National Festival 2020.

Traditional doxology

àtúnṣe
Gworok (Tyap):

Uza u nwuak kai nda;

A̠ ti̠n ufa ci̠p;

Á̠ shyio usa̠rag

Á̠ nat uyit, á̠ bai bi̠ nyam.

Za̠m!

Also styled: Uza u nwuak kai nda; Oe ti̠n ufa ci̠p; Oe shyio usarag Oe nat uyit, oe bai bi̠ nyam. Zoem!

Translation

"May God Almighty provide us with His peace;

Deliver us from misfortune;

Bountifully multiply us

And provide us abundantly in the New Year.

Amen!"

Àwọn àwòrán

àtúnṣe
  • Abwoi religion
  • Ayet Atyap annual cultural festival
  • Festivals in Nigeria

Àwọn ìtọ́ka sí

àtúnṣe
  1. Buhari, Reuben (January 14, 2010). "Nigeria: Kagoro Home to Afan Cultural Festival". All Africa. This Day (Lagos). Retrieved September 14, 2020. 
  2. Kezi, Julius B. (January 6, 2016). "2016 Afan Festival: Kaduna Promises Partnership In Tourism Development". The Dream Daily. Retrieved September 14, 2020. 
  3. 3.0 3.1 "Celebrating Kagoro’s festival of hunters". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-07-31. 
  4. Afuwai, Yanet. The Place of Kagoro in the History of Nigeria. 
  5. "Kagoro Hills of Kaduna State". Nigeria Galleria. Retrieved September 14, 2020. 
  6. 6.0 6.1 6.2 (in English) Kaduna State: Everyone's Handbook. Kano, Nigeria: Triumph Publishing Ltd.. 1982. pp. 109–111. ISBN 978-188-006-6. 
  7. "Festivals in Kaduna State". Retrieved September 14, 2020. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]