Afe Olowookere
Afe Olowookere je olóṣèlú ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà lati Ìpínlẹ̀ Ondo ni Naijiria . Ó sìn gẹ́gẹ́ bí ọmọ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin tí ó ń ṣojú ẹkùn ìdìbò Àríwá Akurẹ́. Lásìkò ti Olowookere fi se ise àkànṣe fun anfaani awon eeyan re. [1] [2]
Afe Olowookere | |
---|---|
Member of the House of Representatives | |
In office May 2015 – May 2019 | |
Constituency | Akure North/Akure South |