African University of Science and Technology

African University of Science and Technology jẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ àkànṣe kọ́mpútà àti ìmọ̀-jíjáde lágbàáyé níbi tí wọ́n ti ń fúnni ní ètò ẹ̀kọ́ àkànṣe àti ọ̀gá káàkiri agbègbè àti ayé gíga ní ìlú Àbújá ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ilé-ẹ̀kọ́ náà ni wọ́n dá sílẹ̀ ní ọdún 2007 gẹ́gẹ́ bí apá àkọ́kọ́ ti ètò ilé-ẹ̀kọ́ àkànṣe àgbáyé Pan-Africaàjọ Nelson Mandela ṣe àlàyé rẹ̀. Ilé-ẹ̀kọ́ náà ń pèsè àwọn ètò ẹ̀kọ́ ọ̀gá ní ẹ̀ka máàrún: Ìmọ́ Computer Science and Management of Information Technology, ìmọ́ Material Science and Engineering, ìmọ́ Petroleum Engineering, ìmọ́ Pure and Applied Mathematics, àti ìmọ́ Space & Aerospace Sciences. Wón sì tún fún nì ní àmì ẹ̀yẹ olùkọ́jáwé ní Public Administration and Public Policy.

African University of Science and Technology
Fáìlì:African Institute of Science and Technology logo.png
Established2007 (2007)
TypePrivate
PresidentAzikwe Peter Onwalu (acting)
LocationAbuja, Nigeria
9°00′04″N 7°25′19″E / 9.001°N 7.422°E / 9.001; 7.422Coordinates: 9°00′04″N 7°25′19″E / 9.001°N 7.422°E / 9.001; 7.422
CampusUrban
Former namesAfrican Institute of Science and Technology
AffiliationsNelson Mandela Institution
Websiteaust.edu.ng
Àmì ẹ̀yẹ African Institute of Science and Technology

Àwọn ojú-ewé lókèèrè

àtúnṣe