Africana (artifacts)
Africana ni àwọn ohun èlò bí ìwé, ère, àti àwòrán tí ó jẹ́ ti orílẹ̀ èdè Áfríkà tí ó sì sọ̀rọ̀ nípa ilẹ̀, ìtàn àti àsà ti Áfríkà.[1][2][3]
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé àwọn ohun èlò yí sọ nípa àwọn oríṣiríṣi ibi ní Áfríkà, ọ̀pọ̀lọpọ̀ wọn dá lórí ìtàn ìwọ oòrùn Áfríkà.[4]
Díẹ̀ nínú àwọn ohun èlò Africana
àtúnṣeÀwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedmerriam-webster
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedtfd
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs nameddictionary.com
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedstellenbosh
Àwọn ìwé tí ó sọ nípa wọn
àtúnṣe- Ensiklopedie van die wêreld, deel 1. Stellenbosch: Albertyn, 1992. ISBN 0-949948-18-7
- Godfrey, Denis (September 1973). "Collecting Africana". Lantern 23 (1).
- Schumann, Annie (September 1968). "J.C.N. Humphreys – Africana collector of distinction". Lantern 18 (1).
- Smith, Anna (September 1953). "The Africana Museum Johannesburg". Lantern 3 (2).
- Standard Encyclopaedia of Southern Africa, part 1. Cape Town: Nasou, 1970.
- Wagener, F.J. (April 1957). "Africana". Lantern 6 (4).