Agathe Uwilingiyimana
Agathe Uwilingiyimana (23 May 1953 – 7 April 1994), tí àwọn míràn mọ̀ sí Madame Agathe,[1] jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ ède Rwanda nígbà ayé rẹ̀. Òun ni ó jẹ́ mínísítà àgbà fún orílẹ̀ ède Rwanda láti ọjọ́ kejìdínlógún oṣù keje di 1993 títí di ìgbà tí wọ́n ṣekú pá ní ọjọ́ keje oṣù kẹfà ọdún 1994. Òun ni ó dípò adarí orílẹ̀ ède Rwanda mú láàrin ìgbà tí wọ́n pa Juvénal Habyarimana sí ìgbà tí wọ́n ṣekú pa òun náà.
Agathe Uwilingiyimana | |
---|---|
4th Prime Minister of Rwanda | |
In office 18 July 1993 – 7 April 1994 | |
Ààrẹ | Juvénal Habyarimana |
Asíwájú | Dismas Nsengiyaremye |
Arọ́pò | Jean Kambanda |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Nyaruhengeri, Butare, Rwanda-Urundi | 23 Oṣù Kàrún 1953
Aláìsí | 7 April 1994 Kigali, Kigali province, Rwanda | (ọmọ ọdún 40)
Cause of death | Assassination |
Resting place | Rwanda National Heroes Cemetery |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Republican Democratic Movement |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Ignace Barahira (m. 1976; their deaths 1994) |
Alma mater | National University of Rwanda |
Religion | Catholicism |
Òun ni obìnrin àkọ́kọ́ láti jẹ́ mínísítà àgbà fún orílẹ̀ ède Rwanda, òun sì nìkan ni obìnrin láti di ipò náà mú.
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Frederik Grünfeld, Anke Huijboom (2007). The Failure to Prevent Genocide in Rwanda: The Role of Bystanders. Martinus Nijhoff Publishers. ISBN 9789004157811. https://books.google.com/books?id=9Tq_zbETHHwC&q=%22madame+agathe%22&pg=PA158.