Àdìjọ ìtanná

(Àtúnjúwe láti Agbára iná)

Àdìjọ ìtanná tabi àdìjọ iná (electric charge) adamo ipilese ifipamo awon igbonwo abeatomu ti o n so bi abasepo inagberigberin won se je. Ohun ti o ba ni agbara ina n pese papa inagberingberin eyi si n nipa lori re. Ibasepo larin agbara ina to n gbera lo ati papa inagberingberin ni o n fa Ipa inagberingberin (electromagnetic force), ti o je ikan larin merin ipilese ipa.

Agbára ìtanná.