Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Àríwá Aba

Agbegbe Ijoba Ibile Ariwa Aba je ijoba ibile ni Ipinle Abia to wa ni Nàìjíríà.[1] A dá ìjọba ìbílè Aba North kalẹ̀ ní odun 1991.[2] Olú ìlú ìjọba ìbílè náà sì ni Eziama Uratta.[3].Àwon ẹ̀yà igbo ni ó pò ní ìjọba ìbílè yìí.[4] Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn olùgbé ìjọba ìbílè yìí jé Kristẹni àti àsin òrìṣà tí wọn sì ún sọ èdè Igbo tàbí Inglisi.[5]

Aba North
Aba North is located in Nigeria
Aba North
Aba North
Location in Nigeria
Coordinates: 5°20′N 7°19′E / 5.333°N 7.317°E / 5.333; 7.317Coordinates: 5°20′N 7°19′E / 5.333°N 7.317°E / 5.333; 7.317
Country Nigeria
StateAbia State
Headquarters at:Eziama Urata
Government
 • Local Government ChairmanChief Victor Ubani 
 • Local Government Deputy ChairmanMrs. Joy Iwuchukwu
Area
 • Total23 km2 (9 sq mi)
Population
 (2006 census)
 • Total107,488
3-digit postal code prefix
450
ISO 3166 codeNG.AB.AN

Àtòjọ àwọn ìlú ni ìjọba ìbílè Abá North

àtúnṣe

Àwọn ìlú yìí ni:

  • Ogbor
  • ụmụ ọla - egbelu
  • ụmụ ọla - Okpulor
  • Eziama
  • Osusu
  • Umuokoji

Ètò ọ̀rọ̀ ajé agbegbe Ijoba Ibile Ariwa Aba

àtúnṣe

Agbegbe Ijoba Ibile Ariwa Aba ni ọjà Ariaria International Market, ọjà Ariaria jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọjà tí ó tóbi jù ni Nàìjíríà.[7]

Àwọn Ìtókasí

àtúnṣe
  1. Brinkmann, Robert; Garren, Sandra J. (2018-04-30) (in en). The Palgrave Handbook of Sustainability: Case Studies and Practical Solutions. Springer. ISBN 978-3-319-71389-2. https://books.google.com/books?id=VCRZDwAAQBAJ&q=aba+north&pg=PA316. 
  2. NigeriaGalleria (2021). "Brief History of Abia State". 
  3. "Aba North LGA". www.finelib.com. Retrieved 2022-07-15. 
  4. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named :0
  5. Nigeria, Media (2022-02-15). "History Of Aba North LGA, Abia State". Media Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2022-10-16. Retrieved 2022-07-15. 
  6. "List of Towns and Villages in Aba North LGA". Nigeria Zip Codes (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2014-02-14. Retrieved 2022-07-15. 
  7. "Aba North Local Government Area". www.manpower.com.ng. Retrieved 2022-09-07.