Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Arochukwu
Agbegbe Ijoba Ibile Arochukwu tí àwọn miran ún pè ní Arochuku tàbí Aro Oke-Igbo jẹ́ ijoba ibile ni Ipinle Abia, orílè-èdè Nàìjíríà. Oun ni ilé fún àra ẹ̀yà igbo kan, tí wón ún jẹ́ Aro. Ẹ̀yà náà wá láti ìdílé márùn-ún, Abam, Aro, Ihechiowa, Ututu àti Ìṣù.
Arochukwu Aro-Okigbo | |
---|---|
Country | Nigeria |
State | Abia State |
Area | |
• Total | 524 km2 (202 sq mi) |
Population | |
• Ethnicities | Igbo, Ibibio, and Akpa |
• Religions | Christianity, Traditional religions |
3-digit postal code prefix | 442 |
ISO 3166 code | NG.AB.AR |
Èdè
àtúnṣeÀwọn èdè tí wọ́n ún sọ ní ìjọba ìbílè Arochukwu ni:[1]
Itokasi
àtúnṣe- ↑ "Nigeria - Languages". Ethnologue, 22d edition. Feb 2019.