Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Ibi

Agbegbe Ijoba Ibile Ibi je ijoba ibile ni Ipinle Taraba towa ni Nigeria. Ibujoko re wa ni ilu Ibi.