Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Irepodun/Ifelodun

Agbegbe Ijoba Ibile Irepodun/Ifelodun je ijoba ibile ni Ipinle Ekiti towa ni Nigeria. Ibujoko re wa ni ilu Igede-Ekiti.

Ilé Ìjọsìn Anglican, Igede-Ekiti, Ìpínlẹ̀ Ekiti.