Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Kuje

Ìjoba ìbílè ní Ìlú Àbújá

Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Kuje jé ara àwon ìjoba ibile tí ó wà ní Àbújá, olú-ìlú Naijiria. Ìjoba ìpínlè náà ní ilè 1888km square àti olùgbé 97,233 gegebi ounka ènìyàn tí odun 2006 se so [1]. Koodu ifiweranse ìjoba ìbílè Kuje ni 903101 [2]

Awon ìlú tí ówà ní Ijoba Ibile Kuje

àtúnṣe

•Damakusa •Bugako •Chida •Jeli •Kiyi •Lafiya •Tuage •Rubbochi [3]


  1. "Kuje (Local Government Area, Nigeria)". Population Statistics, Charts, Map and Location. 2016-03-21. Retrieved 2022-03-20. 
  2. "Kuje Zip Code (Postal Code) - Abuja". Nigeria Postcode. 2018-09-02. Retrieved 2022-03-20. 
  3. "Kuje Local Government Area". Nigeria Business Directory - Find Companies, People & Places in Nigeria. Retrieved 2022-03-20.