Agbègbè Antárktìkì Brítánì

British Antarctic Territory (BAT) je idasi ni Antarctica to je ti orile-ede Britani gege bi ikan ninu awon Agbegbe Okere Britani merinla re.

British Antarctic Territory

Flag of the British Antarctic Territory
Àsìá
Coat of arms ilẹ̀ the British Antarctic Territory
Coat of arms
Motto: Research and discovery
Orin ìyìn: God save the Queen
OlùìlúRothera (Main base)
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaEnglish (de facto)
ÌjọbaConstitutional Monarchy
• Monarch
Queen Elizabeth II
Ìdásílẹ̀
• Claimed
1908
Ìtóbi
• Total
1,709,400 km2 (660,000 sq mi)
Alábùgbé
• Estimate
250
OwónínáPound Sterling (GBP)