Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Àríwá Aba
(Àtúnjúwe láti Agbegbe Ijoba Ibile Ariwa Aba)
Agbegbe Ijoba Ibile Ariwa Aba je ijoba ibile ni Ipinle Abia to wa ni Nàìjíríà.[1] A dá ìjọba ìbílè Aba North kalẹ̀ ní odun 1991.[2] Olú ìlú ìjọba ìbílè náà sì ni Eziama Uratta.[3].Àwon ẹ̀yà igbo ni ó pò ní ìjọba ìbílè yìí.[4] Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn olùgbé ìjọba ìbílè yìí jé Kristẹni àti àsin òrìṣà tí wọn sì ún sọ èdè Igbo tàbí Inglisi.[5]
Aba North | |
---|---|
Coordinates: 5°20′N 7°19′E / 5.333°N 7.317°ECoordinates: 5°20′N 7°19′E / 5.333°N 7.317°E | |
Country | Nigeria |
State | Abia State |
Headquarters at: | Eziama Urata |
Government | |
• Local Government Chairman | Chief Victor Ubani |
• Local Government Deputy Chairman | Mrs. Joy Iwuchukwu |
Area | |
• Total | 23 km2 (9 sq mi) |
Population (2006 census) | |
• Total | 107,488 |
3-digit postal code prefix | 450 |
ISO 3166 code | NG.AB.AN |
Àtòjọ àwọn ìlú ni ìjọba ìbílè Abá North
àtúnṣeÀwọn ìlú yìí ni:
- Ogbor
- ụmụ ọla - egbelu
- ụmụ ọla - Okpulor
- Eziama
- Osusu
- Umuokoji
- uratta.[6]
Ètò ọ̀rọ̀ ajé agbegbe Ijoba Ibile Ariwa Aba
àtúnṣeAgbegbe Ijoba Ibile Ariwa Aba ni ọjà Ariaria International Market, ọjà Ariaria jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọjà tí ó tóbi jù ni Nàìjíríà.[7]
Àwọn Ìtókasí
àtúnṣe- ↑ Brinkmann, Robert; Garren, Sandra J. (2018-04-30) (in en). The Palgrave Handbook of Sustainability: Case Studies and Practical Solutions. Springer. ISBN 978-3-319-71389-2. https://books.google.com/books?id=VCRZDwAAQBAJ&q=aba+north&pg=PA316.
- ↑ NigeriaGalleria (2021). "Brief History of Abia State".
- ↑ "Aba North LGA". www.finelib.com. Retrieved 2022-07-15.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs named:0
- ↑ Nigeria, Media (2022-02-15). "History Of Aba North LGA, Abia State". Media Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2022-10-16. Retrieved 2022-07-15.
- ↑ "List of Towns and Villages in Aba North LGA". Nigeria Zip Codes (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2014-02-14. Retrieved 2022-07-15.
- ↑ "Aba North Local Government Area". www.manpower.com.ng. Retrieved 2022-09-07.