Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Gúúsù-Ìwọòrùn Èkìtì

Agbegbe Ijoba Ibile Guusu-Iwoorun Ekiti je ijoba ibile ni Ipinle Ekiti towa ni Nigeria. Ibujoko re wa ni ilu Ilawe-Ekiti.