Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Gúúsù Nnewi

Àgbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Gúúsù Ńnéwi jẹ́ ọ̀kan lára ìjọba-ìbílẹ̀ mọ̀kànlélógún tí ó wà Ìpínlẹ̀ Anambra ní orílè-èdè Nàìjíríà.[1] Ìlú Ukpor ni Olú-ìlú ìjọba-ìbílẹ̀ Gúúsù Ńnéwi.[2] Wọ́n dá a sílẹ̀ ní ọdún 1991 pẹ̀lú àwọn ìjọba ìbílẹ̀ mọ̀kànlélógún yòókù.[3] Àwọn olùgbé ìjọba-ìbílẹ̀ náà tó mílíọ́nù kan. Iṣẹ́ ̀agbẹ̀ àti kárà kátà ni àwọn olùgbe ibe yàn laa ayó .Esin igbabo ni esin wa

Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Gúúsù Nnewi

Àwọn gbajúmọ̀ ìlú tí wọ́n wà ní ìjọba ìbílẹ̀ Gúúsù Ńnewi àtúnṣe

Yàtọ̀ sí olú-ìlú ìjọba ìbílẹ̀ náà, àwọn ìlú gbajúmọ̀ tí wọ́n tún wà lábẹ́ ìjọba ìbílẹ̀ Gúúsù Ńnéwi ni; Ekwulumili, Amichi, Azigbo, Unubi, Ezinifite, Osumenyi àti Utuh. [4]

Àwọn Ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. Kabir, Olivia (2018-12-21). "Local governments in Anambra state and their towns". Legit.ng - Nigeria news. Retrieved 2019-11-16. 
  2. "Light Of The Nation". Anambra State Government. Archived from the original on 2019-11-16. Retrieved 2019-11-16. 
  3. "History of Anambra state". Oganiru Anambra. 2019-11-12. Archived from the original on 2019-11-16. Retrieved 2019-11-16. 
  4. "Nnewi South L.G.A List of towns and villages". Nigeria Zip Codes (in Èdè Ruwanda). Retrieved 2019-11-16. 

5. https://www.manpower.com.ng/places/lga/121/nnewi-south