Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Moba

(Àtúnjúwe láti Agbegbe Ijoba Ibile Moba)

Agbegbe Ijoba Ibile Moba je ijoba ibile ni Ipinle Ekiti towa ni Nigeria. Ibujoko re wa ni ilu Otun-Ekiti.