Ní agbo-ilé Yorùbá àtijọ́, àwọn mọ̀lẹ́bí tí wọn kì í ṣẹ́ tí ìyá, bàbá, àti àwọn ọmọ nìkan ni wọ́n máa ń gbé ní bẹ̀. Ọkùnrin tí ó dàgbà jù lọ ni ó máa n jẹ olórí ebí. Kòsí àníàní pé àwọn ọkùnrin máa ń ní ìyàwó púpọ̀ ní ayé àtijọ́, tí ìyàwó kọ̀ọ̀kan sì máa n ní ìyàrá ti rẹ̀ lọ́tọ̀. Wọ́n máa ń kọ́ ilé náà ni onílé pẹ̀tẹ́ẹ́sì pẹ̀lú agbo ní ìwájú tàbí ní ẹ̀yìn [1].

Agbo-ilé

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "The Yoruba family". United Nations University. Retrieved 2022-05-21.