Agnes Yewande Savage (tí a bí ní ọjọ́ kànlẹ́lógún oṣù kejì ọdún 1906 tí ó sì fi ayé sílè ní ọjọ́ keje oṣù kẹsàn-án ọdún 1964)[1] jẹ́ onímọ̀ ìṣègùn òyìnbó ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti obìnrin àkọ́kọ́ ní Ìwọòrùn Áfíríkà láti di Dókítá alábẹ́rẹ́.[2][3][4][5][6] Savage jẹ́ obìnrin àkọ́kọ́ ní ìwọ̀ oòrùn ilẹ̀ Áfríkà láti gba àmì-ẹ̀yẹ nínú ìmọ̀ ìṣègùn òyìnbó, ó gba àmì-ẹ̀yẹ first-class ní Yunifásitì Edinburgh ní ọdún 1929 nígbà tí ó jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́tàlélógún.[2][4]

Agnes Yewande Savage
Ọjọ́ìbíỌjọ́ kànlẹ́lógún oṣù kejì ọdún 1906
Edinburgh, Scotland
AláìsíSeptember 7, 1964(1964-09-07) (ọmọ ọdún 58)
Orílẹ̀-èdè
Iléẹ̀kọ́ gíga
Iṣẹ́onímọ̀ ìṣègùn òyìnbó
Gbajúmọ̀ fún
Parent(s)
Àwọn olùbátanRichard Gabriel Akinwande Savage (àwọn arákùnrin)

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Deaths". The Times: pp. 1. 10 September 1964. 
  2. 2.0 2.1 Mitchell, Henry (November 2016). "Dr Agnes Yewande Savage – West Africa's First Woman Doctor (1906-1964)". Centre of African Studies. Archived from the original on 14 April 2019.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. "CAS Students to Lead Seminar on University's African Alumni, Pt. IV: Agnes Yewande Savage" (in en-US). CAS from the Edge. 16 November 2016. https://centreofafricanstudies.wordpress.com/2016/11/16/cas-students-to-lead-seminar-on-universitys-african-alumni-pt-iv-agnes-yewande-savage/. 
  4. 4.0 4.1 Tetty, Charles (1985). "Medical Practitioners of African Descent in Colonial Ghana". The International Journal of African Historical Studies 18 (1): 139–144. doi:10.2307/217977. JSTOR 217977. PMID 11617203. 
  5. "Agnes Yewande Savage (1906 – 1964)" (in en). The University of Edinburgh. Archived from the original on 2018-11-24. https://web.archive.org/web/20181124203251/https://webcache.googleusercontent.com/search?q=cache:v4vUh9wytN4J:https://www.ed.ac.uk/alumni/services/notable-alumni/alumni-in-history/agnes-yewande-savage+&cd=2&hl=en&ct=clnk&gl=us. 
  6. Ferry, Georgina (November 2018). "Agnes Yewande Savage, Susan Ofori-Atta, and Matilda Clerk: three pioneering doctors" (in English). The Lancet 392 (10161): 2258–2259. doi:10.1016/S0140-6736(18)32827-7. ISSN 0140-6736. https://www.thelancet.com/journals/lancet/article/PIIS0140-6736(18)32827-7/fulltext.