Ahmad Babba Kaita

Olóṣèlú Nàìjíríà ni yii

Ahmad Babba Kaita jẹ́ ọmọ ilé ìgbìmò aṣòfin orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. [1] [2] Ó jẹ́ tó ń ṣojú ẹgbẹ́ Congress for Progressive Change ni ẹkùn ìdìbò Kankia / Ingawa / Kusada ti Ipinle Katsina, Nigeria. O di aṣoju ni ọdun 2011. [3]

Ahmad Babba Kaita
Senato
In office
2018–2023
AsíwájúBukar Mustapha
Arọ́pòNasir Sani Zangon Daura
ConstituencyKatsina North
House of Representatives
In office
2011–2018
AsíwájúKabir Ahmad Kofa
ConstituencyKankia/Ingawa/Kusada
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbíOṣù Kẹ̀sán 1968 (ọmọ ọdún 56)
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Ẹgbẹ́ olóṣèlúAll Progressive Congress (APC)
Congress for Progressive Change (CPC) and a Peoples Democratic Party (PDP)
ResidencePort Harcourt
ProfessionOlóṣèlú

abẹlẹ

àtúnṣe

Wọ́n bí Kaita ní ọjọ́ kẹsàn-án oṣù kẹjọ ọdún 1968, ó sì wá láti ilẹ̀ Hausa àti Fulani . O kọ ẹkọ alakọbẹrẹ rẹ ni Sada Primary School ni Kankia láàrin ọdun 1974 ati 1980. O kọ kíkà Al-Qur’an ni pdp baba rẹ, lẹhinna o lọ si ile-ẹkọ girama rẹ ni Kufena College Wusasa Zaria ni ìpínlè Kaduna laarin ọdun 1980 si 1985. [4]

Awọn itọkasi

àtúnṣe