Ahmad Hasan Amrohi
Ọ̀gbẹ́niAhmad Hasan Amrohi (eni tí a tún mọ̀ sí Muhaddith Amrohi, tí wọ́n bí lọ́jọ́ kejìdínlógún oṣù kẹta 1850 ọdún 1912) jẹ́ jẹ́ ọ̀mọ̀wé làmìlaka Mùsùlùmí ọmọ Indian tí ó jẹ́ ọ̀gá àkọ́kọ́was Madrasa Shahi ní Moradabad. Ó jẹ́ akẹ́kọ̀ọ́-àná ti Darul Uloom Deoband, tí ó sìn tún jẹ́ ọ̀kan lára olùdásílẹ̀ ẹgbẹ́ Mahmud Hasan Deobandi ti Thamratut-Tarbiyat. Ó jẹ́ aláṣẹ ọmọlẹ́yìn Imdadullah Muhajir Makki[3][4].
Mawlānā Ahmad Hasan Amrohi | |
---|---|
Muhaddith Amrohi | |
Ọ̀gá-àgbà àkọ́kọ́ ti Madrasa Shahi | |
In office 1879–1885 | |
Asíwájú | "post established" |
Arọ́pò | "àìmọ̀" |
Ọ̀gá-àgbà àkọ́kọ́ ti Jamia Islamia Arabia Amroha | |
Asíwájú | "post established" |
Arọ́pò | Abdur Rahman Siddīqi Sandelwi[1] |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 1850 Amroha, Moradabad district |
Aláìsí | 1912 Amroha, Moradabad, British India |
Alma mater | Darul Uloom Deoband |
Ìgbèsi Àye Ahmad Hasan Amrohi
àtúnṣeAhmad Hasan ni á bisi Amroha ni ọdun 1850 si àgbègbè Moradabad. Arakunrin naa kawè ibẹẹrẹ lati Sayyid Rafat Ali, Karim Bakhsh Bakhshi, Muhammad Hussain Jafri atipe ó kọ iṣẹ iṣègun pẹlu Amjad Ali Khan[5]. Lẹyin naa o lọsi Meerut lati kẹẹkọ giga pẹ̀lu Muhammad Qasim Nanautawi[6]. O kawè jàdè ni ọdun 1290AH lati Darul Uloom Deoband pẹlu Mahmud Hasan Deobandi ati Fakhrul Hasan Gangohi[6].
Ahmad jẹ ọmọlẹyin Imdadullah Muhajir Makki ninu ijọ Sufi to si tun gba hadith pẹlu Ahmad Ali Saharanpuri ati Shah Abdul Ghani. Hasan di ọga ilè ẹkọ ti Madrasa Qasmia èyi ti ólukọ rẹ Nanautawi dasilẹ ni Khurja[7][8] .
Hasan ku latari plague ni óṣu March, ọdun 1912[9]. Adura isinku rẹ ni Hafiz Muhammad Ahmad[10] dari ti Kifayatullah Dehlawi, Habibur Rahman Usmani ati Mahmud Hasan Deobandi si daro ikurẹ[11].
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Fareedi 2009, p. 175.
- ↑ Saharanpuri, Khalil Ahmad (2001). Mabahith fi 'Aqa'id Ahl al-Sunna. Dar al-Fath. pp. 101.
- ↑ Allāh, ‘Abd (2013-01-25). "Mawlana Sayyid Ahmad Hasan Amrohi". Ḥayāt al-‘Ulamā’. Retrieved 2023-09-15.
- ↑ "Ahmad Hasan's Instagram, Twitter & Facebook on IDCrawl". IDCrawl. 2020-01-01. Retrieved 2023-09-15.
- ↑ Fareedi 2000, p. 369–370.
- ↑ 6.0 6.1 Mansoorpuri 2014, p. 156.
- ↑ Fareedi 2000, p. 371.
- ↑ Imdadul Haq Bakhtiyar (16 October 2020). "سید العلماء قاسم ثانی حضرت مولانا سید احمد حسن محدث امروہی: حیات وخدمات" (in ur). Baseerat Online. https://www.baseeratonline.com/122482.
- ↑ Mansoorpuri 2014, p. 156-157.
- ↑ Qasmi 1999, p. 62.
- ↑ Fareedi 2000, p. 416-422.