Yunifásítì Àmọ́dù Béllò

yunifasiti gbogbogbo ni nigeria
(Àtúnjúwe láti Ahmadu Bello University)

Yunifásitì Ahmadu Bello (ABU) jẹ́ ilé-ẹ̀kọ́ gíga àgbà ti ìjọba apapọ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà tí wà ní ìlú ZariaÌpínlẹ̀ Kaduna ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Wọ́n dá ilé-ẹ̀kọ́ yí sílẹ̀ ní ọjọ́ Kẹrin oṣù Kẹwàá, ọdún 1962. [1][2]

Fásitì Ahmadu Bello
Ahmadu Bello University
EstablishedOctober 4, 1962
TypePublic
LocationZaria, Kaduna State, Nigeria
CampusUrban
Websitehttp://www.abu.edu.ng/

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Ahmadu Bello University - university, Zaria, Nigeria". Encyclopedia Britannica. Retrieved 2020-07-01. 
  2. Unit, Web Management (2019-03-06). "Ahmadu Bello University". Home. Retrieved 2020-07-01.